Wednesday, 2 October 2013

Lyrics: King Oogbodo – Ife Ikeja


Intro
Yeahhhhhhhhhhh!
Oseyiza King Oogbodo
Blood Entertainment
Don Drim production
Ikeja love you know
Ife Ikeja you know
Ikeja luvvvv


Verse 1
Ta lo to be lati so pe oun o mo Ikeja to wa l’Eko
Eko t’awon Oloyinbo pe ni Lagos State, Nigeria
Ikeja yen men
Ko s’oun ti o si ni be
To ba je hustler
To ba hustle ni Ikeja
Gbogbo dreams e lo ma di reality
Gba bi mo se so fun e
Emi ti hustle ni Ikeja
So e ma je ko ya yin lenu pe mo n p’ariwo Ikeja
T’omode ba da
E je ka fi yin fun
Ibi pelebe l’emi ti n b’ole
O ja si pe
Mi o n ki paro
O to ni mo de n so fun yin
Pe ninu gbogbo ilu to wa l’Eko
Ikeja, Surulere, Apapa ati bebelo
Ikeja o yato jo

Chorus
Ikeja baba ni se
IKJ baba ni se
Ikeja baba ni se
IKJ baba ni se
Ikeja mo ni’fe e
IKJ I love ya
Ikeja mo ni’fe e
IKJ I love ya

Verse 2
Nigbati mo ma ko ko de’Keja
Inu mi dun bi talaka to se je 1 million dollars
Mo fo s’oke
Mo de pariwo ayo
Tori mo ti n ma n gbo n pa Ikeja tipe tipe
Allen Avenue, Opebi, Awolowo Way ati bebelo
Aye wa ni Ikeja
Aye to ju aye lo
Ti n ba pa’ro
E ma bo mi l’asiri
Hotel to da ju ni 9ja
Ikeja lo wa
Airport to da ju nko
Ikeja lo wa
Ijoba Eko na nko
Ikeja lo wa
Ijoba Eko lo de n control gbogbo nkan to n’sele l’Eko
Eyin ti Lekki, eyin ti Mushin, bo de j’eyin ti Yaba
Gbogbo nkan te ba fe se

Repeat chorus

Verse 3
So ko need ka ma pariwo enu ju
Tori gbogbo wa la mo pe
Ika o do’gba
Isu ati’yan o de n ki se’gbe
In the same vein
Ikeja o ki n se’gbe eyin ilu yoku to wa l’Eko
Ele yi o n ki soro ka ma taka
Ko de n ki n se’jakadi
Mathematics ni
1 + 1 is equal to 2

Repeat chorus (3x)

Instrumental and adlibs till end

 

No comments:

Post a Comment